Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Sefanaya 3:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn olóyè rẹ̀ ní ìwọ̀ra bíi kinniun tí ń bú ramúramù; àwọn onídàájọ́ rẹ̀ dàbí ìkookò tí ń jẹ ní aṣálẹ̀ tí kì í jẹ ẹran tí ó bá pa lájẹṣẹ́kù di ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Sefanaya 3

Wo Sefanaya 3:3 ni o tọ