Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 9:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dá a lóhùn pé, “Bí a bá tọ eniyan Ọlọrun yìí lọ nisinsinyii, kí ni a óo mú lọ́wọ́ lọ fún un? Oúnjẹ tí ó wà ninu àpò wa ti tán, bẹ́ẹ̀ sì ni kò sí nǹkankan lọ́wọ́ wa tí a lè fún un. Àbí kí ni a óo fún un?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9

Wo Samuẹli Kinni 9:7 ni o tọ