Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Iranṣẹ náà dá a lóhùn, ó ní, “Dúró ná, eniyan Ọlọrun kan wà ní ilẹ̀ yìí, tí gbogbo eniyan ń bu ọlá fún, nítorí pé gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀ níí máa ń ṣẹ. Jẹ́ kí á lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀, bóyá ó lè sọ ibi tí a óo ti rí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà fún wa.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 9

Wo Samuẹli Kinni 9:6 ni o tọ