Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 6:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ará ìlú Beti ṣemeṣi ń kórè ọkà lọ́wọ́ ní àfonífojì náà, bí wọ́n ti gbójú sókè, wọ́n rí àpótí ẹ̀rí. Inú wọn dùn pupọ pupọ bí wọ́n ti rí i.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:13 ni o tọ