Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 6:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mààlúù yìí bá doríkọ ọ̀nà Beti Ṣemeṣi, wọ́n ń lọ tààrà láì yà sọ́tùn-ún tabi sósì. Wọ́n ń ké bí wọ́n ti ń lọ. Àwọn ọba Filistini maraarun tẹ̀lé wọn títí dé odi Beti Ṣemeṣi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 6

Wo Samuẹli Kinni 6:12 ni o tọ