Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí ó fi jẹ́ pé títí di òní olónìí, àwọn babalóòṣà oriṣa Dagoni ati gbogbo àwọn tí wọ́n máa ń bọ ọ́ kò jẹ́ tẹ ẹnu ọ̀nà ilé oriṣa Dagoni tí ó wà ní ìlú Aṣidodu, dídá ni wọ́n máa ń dá a kọjá.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 5

Wo Samuẹli Kinni 5:5 ni o tọ