Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 5:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó tún di òwúrọ̀ kutukutu wọ́n tún bá a tí ère náà tún ti ṣubú tí ó tún ti dojú bolẹ̀ níwájú àpótí OLUWA, ati pé orí ati ọwọ́ rẹ̀ mejeeji ti gé kúrò, wọ́n wà nílẹ̀ ní ẹnu ọ̀nà, ara rẹ̀ nìkan ni ó kù.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 5

Wo Samuẹli Kinni 5:4 ni o tọ