Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 4:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí dé ibùdó, gbogbo Israẹli hó ìhó ayọ̀, tóbẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ mì tìtì.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:5 ni o tọ