Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 4:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá ranṣẹ lọ sí Ṣilo láti gbé àpótí ẹ̀rí OLUWA tí ó gúnwà láàrin àwọn Kerubu. Àwọn ọmọ Eli mejeeji, Hofini ati Finehasi, sì tẹ̀lé àpótí ẹ̀rí náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 4

Wo Samuẹli Kinni 4:4 ni o tọ