Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 30:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn igba (200) eniyan tí àárẹ̀ mú pupọ, tí wọn kò lè kọjá odò, ṣugbọn tí wọ́n dúró lẹ́yìn odò Besori; àwọn náà wá pàdé Dafidi ati àwọn tí wọ́n bá a lọ. Dafidi sì kí wọn dáradára.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:21 ni o tọ