Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 30:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó gba gbogbo àwọn ẹran ọ̀sìn pẹlu. Àwọn eniyan náà sì ń dá àwọn ẹran ọ̀sìn náà jọ níwájú Dafidi, wọ́n ń sọ pé, “Ìkógun Dafidi nìyí.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:20 ni o tọ