Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 30:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó mú Dafidi lọ bá wọn.Àwọn ọmọ ogun náà fọ́n káàkiri, wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, wọ́n sì ń jó, nítorí ọpọlọpọ ìkógun tí wọ́n rí kó ní ilẹ̀ àwọn ará Filistia ati Juda.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:16 ni o tọ