Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 30:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi bi í léèrè pé, “Ṣé o lè mú mi lọ sọ́dọ̀ àwọn ọmọ ogun náà?”Ó dáhùn pé, “N óo mú ọ lọ, bí o bá ṣèlérí ní orúkọ Ọlọrun pé o kò ní pa mí, tabi kí o fi mí lé oluwa mi lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 30

Wo Samuẹli Kinni 30:15 ni o tọ