Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá sọ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé, “Ẹ bá mi wá obinrin kan tí ó bá jẹ́ abókùúsọ̀rọ̀, kí n lè lọ ṣe àyẹ̀wò lọ́dọ̀ rẹ̀.”Wọn sì sọ fún un pé, “Obinrin kan wà ní Endori tí ó jẹ́ abókùúsọ̀rọ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:7 ni o tọ