Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Saulu bèèrè lọ́wọ́ OLUWA ohun tí yóo ṣe, OLUWA kò dá a lóhùn yálà nípa àlá tabi nípa Urimu tabi nípasẹ̀ àwọn wolii.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:6 ni o tọ