Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bèèrè pé, “Báwo ló rí?”Obinrin náà dáhùn pé, “Ọkunrin arúgbó kan ló ń bọ̀, ó sì fi aṣọ bora.”Saulu mọ̀ pé Samuẹli ni, ó sì tẹríba.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:14 ni o tọ