Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 28:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá sọ fún un pé, “Má bẹ̀rù, sọ ohun tí o rí fún mi.”Obinrin náà dáhùn pé, “Mo rí ẹbọra kan, tí ń jáde bọ̀ láti inú ilẹ̀.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 28

Wo Samuẹli Kinni 28:13 ni o tọ