Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Bèèrè lọ́wọ́ àwọn ọdọmọkunrin rẹ, wọn yóo sì sọ fún ọ. Ọjọ́ ọdún ni ọjọ́ òní, nítorí náà jẹ́ kí àwọn ọmọkunrin yìí rí ojurere lọ́dọ̀ rẹ. Jọ̀wọ́ mú ohunkohun tí ó bá wà ní àrọ́wọ́tó rẹ fún àwọn iranṣẹ rẹ, ati fún èmi Dafidi, ọmọ rẹ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:8 ni o tọ