Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbọ́ pé ò ń gé irun àwọn aguntan rẹ, mo sì fẹ́ kí o mọ̀ pé àwọn olùṣọ́ aguntan rẹ wà lọ́dọ̀ wa fún ìgbà pípẹ́, n kò sì ṣe wọ́n ní ibi kankan. Kò sí ohun tí ó jẹ́ tiwọn tí ó sọnù ní gbogbo ìgbà tí wọ́n wà ní Kamẹli.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:7 ni o tọ