Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Orúkọ ọkunrin náà ni Nabali, iyawo rẹ̀ sì ń jẹ́ Abigaili. Obinrin náà jẹ́ ọlọ́gbọ́n ati arẹwà, ṣugbọn ọkọ rẹ̀ jẹ́ òǹrorò ati eniyan burúkú. Ìdílé Kalebu ni ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:3 ni o tọ