Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 25:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan wà ní ìlú Maoni tí ń ṣe òwò ní Kamẹli. Ọkunrin náà ní ọrọ̀ lọpọlọpọ; ó ní ẹgbẹẹdogun aguntan (3,000) ati ẹgbẹrun (1,000) ewúrẹ́, Kamẹli níí ti máa ń gé irun aguntan rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 25

Wo Samuẹli Kinni 25:2 ni o tọ