Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ bá lọ gbógun ti àwọn ará Filistia ní Keila, wọ́n pa ọpọlọpọ ninu wọn, wọ́n sì kó àwọn ẹran ọ̀sìn wọn. Bẹ́ẹ̀ ni Dafidi ṣe gba àwọn ará Keila sílẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:5 ni o tọ