Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi tún bèèrè lọ́wọ́ OLUWA lẹ́ẹ̀kan sí i pé, bóyá kí òun lọ tabi kí òun má lọ. OLUWA sì dáhùn pé, “Lọ sí Keila nítorí n óo fún ọ ní ìṣẹ́gun lórí àwọn ará Filistia.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 23

Wo Samuẹli Kinni 23:4 ni o tọ