Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, Jonatani sọ fún Dafidi pé, “Ọ̀la ni ọjọ́ àjọ̀dún oṣù tuntun, àwọn eniyan yóo sì mọ̀ bí o kò bá wá síbi oúnjẹ nítorí ààyè rẹ yóo ṣófo.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:18 ni o tọ