Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 20:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani tún mú kí Dafidi ṣe ìbúra lẹ́ẹ̀kan sí i, pẹlu ìfẹ́ tí ó ní sí i. Nítorí pé, Jonatani fẹ́ràn rẹ̀ bí ó ti fẹ́ràn ẹ̀mí ara rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 20

Wo Samuẹli Kinni 20:17 ni o tọ