Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Èyíkéyìí tí ó bá wà láàyè ninu arọmọdọmọ rẹ yóo máa tọ alufaa yìí lọ láti tọrọ owó ati oúnjẹ lọ́wọ́ rẹ̀. Ẹ̀bẹ̀ ni yóo sì máa bẹ̀, pé kí ó fi òun sí ipò alufaa kí òun baà lè máa rí oúnjẹ jẹ.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:36 ni o tọ