Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:35 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo yan alufaa mìíràn fún ara mi, tí yóo ṣe olóòótọ́ sí mi, tí yóo sì ṣe gbogbo ohun tí mo bá fẹ́ kí ó ṣe. N óo fi ìdí ìdílé rẹ̀ múlẹ̀, yóo sì máa ṣe iṣẹ́ alufaa níwájú ẹni àmì òróró mi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:35 ni o tọ