Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹni tí ń rú ẹbọ náà bá dá a lóhùn pé “Jẹ́ kí á kọ́kọ́ sun ọ̀rá ẹran náà, lẹ́yìn náà kí o wá mú ohun tí ó bá wù ọ́.” Iranṣẹ alufaa náà á wí pé, “Rárá! Nisinsinyii ni kí o fún mi, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, n óo mú un tipátipá.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:16 ni o tọ