Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 2:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé, kí wọ́n tilẹ̀ tó rẹ́ ọ̀rá tí wọ́n máa ń sun kúrò lára ẹran, iranṣẹ alufaa á wá, a sì wí fún ẹni tí ń rú ẹbọ pé kí ó fún òun ninu ẹran tí alufaa yóo sun jẹ, nítorí pé alufaa kò ní gba ẹran bíbọ̀ lọ́wọ́ olúwarẹ̀, àfi ẹran tútù.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 2

Wo Samuẹli Kinni 2:15 ni o tọ