Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí wọ́n ti ń pada bọ̀ wálé, lẹ́yìn tí Dafidi ti pa Goliati, àwọn obinrin jáde láti gbogbo ìlú Israẹli, wọ́n lọ pàdé Saulu ọba, pẹlu orin ati ijó, wọ́n ń lu aro, wọ́n sì ń kọrin ayọ̀ pẹlu àwọn ohun èlò orin.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:6 ni o tọ