Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Dafidi ń ṣe àṣeyọrí ninu àwọn iṣẹ́ tí Saulu ń rán an. Nítorí náà, Saulu fi ṣe ọ̀kan ninu àwọn olórí ogun rẹ̀. Èyí sì tẹ́ àwọn olórí yòókù lọ́rùn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:5 ni o tọ