Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu pàṣẹ fún àwọn iranṣẹ rẹ̀ pé, “Ẹ lọ bá Dafidi sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀ pé, inú ọba dùn sí i lọpọlọpọ, ati pé gbogbo àwọn iranṣẹ ọba fẹ́ràn rẹ̀, nítorí náà ó yẹ kí ó fẹ́ ọmọ ọba.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 18

Wo Samuẹli Kinni 18:22 ni o tọ