Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi iranṣẹ rẹ yìí ti pa àwọn kinniun ati àwọn ẹranko beari rí, aláìkọlà Filistini yìí yóo sì dàbí ọ̀kan ninu wọn, nítorí pé, ó ti pe àwọn ọmọ ogun Ọlọrun alààyè níjà.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:36 ni o tọ