Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 17:35 BIBELI MIMỌ (BM)

n óo tẹ̀lé e lọ, n óo lù ú, n óo sì gba aguntan náà kúrò lẹ́nu rẹ̀. Bí ó bá sì kọjú ìjà sí mi, n óo di ọ̀fun rẹ̀ mú, n óo sì pa á.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 17

Wo Samuẹli Kinni 17:35 ni o tọ