Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:39 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fi OLUWA alààyè tí ó fún Israẹli ní ìṣẹ́gun búra pé, pípa ni a óo pa ẹni tí ó bá jẹ̀bi ọ̀rọ̀ yìí, kì báà jẹ́ Jonatani ọmọ mi.” Ṣugbọn ẹnikẹ́ni kò dá a lóhùn ninu wọn.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:39 ni o tọ