Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọ̀kan ninu àwọn eniyan náà wí fún un pé, “Ebi ń pa gbogbo wa kú lọ, ṣugbọn baba rẹ ti búra pé, ‘Ègbé ni fún ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ẹnu kan nǹkankan lónìí.’ ”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:28 ni o tọ