Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jonatani kò gbọ́ nígbà tí baba rẹ̀ ń fi ìbúra pàṣẹ fún àwọn eniyan náà. Nítorí náà, ó na ọ̀pá tí ó mú lọ́wọ́, ó tì í bọ inú afárá oyin kan, ó sì lá a. Lẹsẹkẹsẹ ojú rẹ̀ wálẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:27 ni o tọ