Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Jonatani bá rápálá gun òkè náà, ọdọmọkunrin tí ó ń ru ihamọra rẹ̀ sì tẹ̀lé e. Jonatani bá bẹ̀rẹ̀ sí bá àwọn ará Filistia jà, wọ́n sì ń ṣubú níwájú rẹ̀, bí wọ́n ti ń ṣubú ni ọdọmọkunrin tí ń ru ihamọra rẹ̀ ń pa wọ́n.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:13 ni o tọ