Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 14:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n bá nahùn pe Jonatani ati ọdọmọkunrin tí ó ń ru ihamọra rẹ̀; wọ́n ní, “Ẹ máa gòkè tọ̀ wá bọ̀ níhìn-ín, a óo fi nǹkankan hàn yín.”Jonatani bá wí fún ọdọmọkunrin náà pé, “Tẹ̀lé mi, OLUWA ti fún Israẹli ní ìṣẹ́gun lórí wọn.”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 14

Wo Samuẹli Kinni 14:12 ni o tọ