Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 13:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ní ọjọ́ ogun yìí kò sí ẹnikẹ́ni ninu àwọn ọmọ ogun Israẹli tí ó ní idà tabi ọ̀kọ̀ lọ́wọ́, àfi Saulu ati Jonatani ọmọ rẹ̀.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13

Wo Samuẹli Kinni 13:22 ni o tọ