Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Owó díẹ̀ ni àwọn Filistia máa ń gbà, láti bá wọn pọ́n ohun ìtúlẹ̀ ati ọkọ́, wọ́n ń gba ìdámẹ́ta owó ṣekeli láti pọ́n àáké ati láti tún irin tí ó wà lára ohun ìtúlẹ̀ ṣe.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 13

Wo Samuẹli Kinni 13:21 ni o tọ