Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 11:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n sọ fún àwọn oníṣẹ́ tí wọ́n wá láti Jabeṣi-Gileadi pé, “Ẹ sọ fún àwọn eniyan yín pé, ní ọ̀sán ọ̀la, a óo gbà wọ́n kalẹ̀.” Nígbà tí àwọn ará Jabeṣi gbọ́ ìròyìn náà, inú wọn dùn gidigidi.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 11

Wo Samuẹli Kinni 11:9 ni o tọ