Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 11:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu bá kó wọn jọ ní Beseki. Ọ̀kẹ́ mẹẹdogun (300,000) ni àwọn tí wọ́n wá láti ilẹ̀ Israẹli, àwọn tí wọ́n wá láti Juda sì jẹ́ ẹgbaa mẹẹdogun (30,000).

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 11

Wo Samuẹli Kinni 11:8 ni o tọ