Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò yìí gan-an ni Saulu ń ti oko rẹ̀ bọ̀, pẹlu àwọn akọ mààlúù rẹ̀. Ó bèèrè pé, “Kí ló ṣẹlẹ̀ tí gbogbo eniyan fi ń sọkún?” Wọ́n bá sọ ohun tí àwọn ará Jabeṣi sọ fún un.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 11

Wo Samuẹli Kinni 11:5 ni o tọ