Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 10:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Saulu dáhùn pé, “Ó sọ fún wa pé, dájúdájú, wọ́n ti rí àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ náà.” Ṣugbọn Saulu kò sọ fún un pé, Samuẹli sọ fún òun pé òun yóo jọba.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:16 ni o tọ