Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọkunrin kan tí ń gbé ibẹ̀ bèèrè pé, “Ta ni baba àwọn wolii wọnyi?” Láti ìgbà náà ni ó ti di àṣà kí àwọn eniyan máa wí pé, “Àbí Saulu náà ti di wolii ni?”

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 10

Wo Samuẹli Kinni 10:12 ni o tọ