Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Kinni 1:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Iyawo meji ni Elikana yìí ní. Ọ̀kan ń jẹ́ Hana, ekeji sì ń jẹ́ Penina. Penina bímọ, ṣugbọn Hana kò bí.

Ka pipe ipin Samuẹli Kinni 1

Wo Samuẹli Kinni 1:2 ni o tọ