Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 7:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA Ọlọrun, o tóbi gan-an! Kò sí ẹni tí ó dàbí rẹ, bẹ́ẹ̀ ni kò sí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn rẹ, nítorí gbogbo ohun tí a ti fi etí wa gbọ́.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 7

Wo Samuẹli Keji 7:22 ni o tọ