Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbé àpótí ẹ̀rí jáde kúrò ní ilé Abinadabu tí ó wà lórí òkè, wọ́n sì gbé e ka orí kẹ̀kẹ́ tuntun kan. Usa ati Ahio ọmọ Abinadabu sì ń ti kẹ̀kẹ́ náà;

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:3 ni o tọ