Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Samuẹli Keji 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kó wọn lọ sí Baala ní Juda láti gbé àpótí ẹ̀rí Ọlọrun wá sí Jerusalẹmu. Orúkọ OLUWA àwọn ọmọ ogun ni wọ́n fi ń pe àpótí ẹ̀rí náà, ìtẹ́ rẹ̀ sì wà lórí àwọn Kerubu tí ó wà lókè àpótí náà.

Ka pipe ipin Samuẹli Keji 6

Wo Samuẹli Keji 6:2 ni o tọ